مَلَكَنِي هَوَاكُمْ عَذَّبَنِي
Ìfẹ́ yín ti gbà mí lọ́kàn, ó sì ti dán mi lòrò.
Yo
الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ يَـا مَـوْلَانَـا
لَا بُـدَّ مِـن فَـنَـاء الْـمُـلْـكُ يَـبْـقَـى لِـلَّـه
Allah, Allah, Allah, Allah, Iwọ Oluwa wa!
Iparun dandan ni; gbogbo ijọba kù fun Allah
مَـلَـكَـنِـي هَـوَاكُـمْ عَـذَّبَـنِـي
وَزَادَنِـي شَـوْقًا وَ قَـلَـقَا
Ifẹ Yin ti gba mi l’ọkan, o si n da mi l’oro
O si n mu ifẹ-ọkan ati aibalẹ-ọkan mi pọ si i
الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ يَـا مَـوْلَانَـا
لَا بُـدَّ مِـن فَـنَـاء الْـمُـلْـكُ يَـبْـقَـى لِـلَّـه
Allah, Allah, Allah, Allah, Iwọ Oluwa wa!
Iparun dandan ni; gbogbo ijọba kù fun Allah
الْـنَّـوَى وَالْـبَـيْـنُ أَقْـلَـقَـنِـي
وَغَـشِـيَ الْـقَـلْـبُ وَ إِحْـتَـرَقَ
Jijinna ati iyasọtọ ti d’aru ọkan mi
Ọkan mi si ṣu, o si ti jona tán
الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ يَـا مَـوْلَانَـا
لَا بُـدَّ مِـن فَـنَـاء الْـمُـلْـكُ يَـبْـقَـى لِـلَّـه
Allah, Allah, Allah, Allah, Iwọ Oluwa wa!
Iparun dandan ni; gbogbo ijọba kù fun Allah
بِـثَـوْبِ رِضَـاكُـمْ كَـفِّـنُـونِـي
بِـبَـابِ حِمَاكُمْ أَلْـحِـدُونِـي
Pẹlu aṣọ iyọnu Yin, ẹ fi ṣe aṣọ-òkú fún mi
Ni oju-ọna ẹnu-ọna ile Yin, ẹ sìn mí sí
الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ الـلَّـهْ يَـا مَـوْلَانَـا
لَا بُـدَّ مِـن فَـنَـاء الْـمُـلْـكُ يَـبْـقَـى لِـلَّـه
Allah, Allah, Allah, Allah, Iwọ Oluwa wa!
Iparun dandan ni; gbogbo ijọba kù fun Allah
وَاكْـتُـبُـوا عَـلَى قَـبْـرِي وَرَقَـةْ
هَـذَا مُـحِـبٌّ قَـدِ احْـتَـرَقْ
Ẹ si kọ sinu iwe kekere kan s’ara saare mi
"Olùfẹ́ kan ti o jona ninu ifẹ-ọkan ni eyi"