قَدْ بَدَا إِلَيَّ نُورُهَا عَشِياً
Her Light Appeared to Me at Dusk
Yo
قَدْ بَدَا إِلَيَّ
نُورُهَا عَشِيَّا
Ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ti farahàn sí mi
ní àsìkò alẹ́
ذَاتٌ فَتَنَتْ فِي حُلَى حُسْنِهَا الْبَرِيَّة
Ẹni tí ó fa gbogbo ìṣẹ̀dá mọ́ra pẹ̀lú ohun ọ̀ṣọ́ ẹwà rẹ̀
أَسْمَاءٌ جَلِيلَةْ
كَمْ شَفَتْ عَلِيَلا
Àwọn orúkọ ọlọ́lá
ọ̀pọ̀ aláìsàn ni wọ́n ti wòsàn
أَمْسَى قَتِيلاً فِي الْهَوَى وَقَضَى الْمَنِيَّةْ
Ó ti di ẹni tí ìfẹ́ pa, ó sì parí ayé rẹ̀
صَا حِ لَا تَلُمْنِي
مَدْحُ الْنَّبِي فَنِّي
Ọ̀rẹ́ mi má ṣe bá mi wí
kíkọ orin ìyìn fún Ànábì ni iṣẹ́ mi
خَمْرِيَ وَ دَنِي مِنْ طِلَا ثَغْرِ هَا الدُرِيَّة
Ọtí mi àti ìkòkò mi láti inú ẹnu rẹ̀ tó dán
صَلَى ذُو الْجَلَالِ
عَلَى الْنَّبِي الْغَا لِي
Ọlọ́run Aláṣẹ ti rọ̀jò ìkẹ́
sára Ànábì ọ̀wọ́n náà
ثُمَّ الْآلِ ذَوِي الْعُلَا الْصَّحْبِ وَالْذُرِيَّة
Àti àwọn ará ilé onípò gíga, àwọn ọmọ lẹ́yìn àti ìran rẹ̀