رَبِّي خَلَقْ طَه مِنْ نُورْ
Olúwa mi dá Taha látinú ìmọ́lẹ̀.
Yo
رَبِّي خَلَقْ طَه مِنْ نُورْ فِيهْ اِحْتِرَامْ
نَادَاهُ أَقْبِلْ يَامُخْتَارْ أَنْتَ اْلأَمِينْ
Olúwa mi dá Taha láti inú ìmọ́lẹ̀ kan tí ọ̀wọ̀ kún fún
Ó pè é pé: "Wá síwájú ìwọ Àyànfẹ́, ìwọ ni Olùfọkàntán"
لَمَّاارْتَقَى الْبَيْتَ الْمَعْمُورْ صَلّى إِمَامْ
وَقَدْ دَنَا مِنْ رَبِّهِ الْبَاهِي الْجَلِيلْ
Nígbà tí ó gòkè lọ sí Ilé Alákúnfúnrẹ́rẹ́, ó kírun gẹ́gẹ́ bí aṣáájú
Ó sì súnmọ́ Olúwa rẹ̀, Ẹni Títàn àti Ọlọ́lá-ńlá
إِنْ رُمْتَ أَنْ تَحْظى بِالْحُورْ يَوْمَ الْزِّحَامْ
صَلِّى عَلَى بَاهِي اْلأَنْوَارْ عَيْنِ الْيَقِينْ
Bí o bá fẹ́ láti jèrè àwọn wúńdíá ọ̀run ní ọjọ́ àpéjọpọ̀
Șe ìkíni fún Ẹni Títàn nínú àwọn ìmọ́lẹ̀, Orísun Ìdánilójú