يَاعُمْدَتِي ياعُدَّتِي
Ìwọ Òpómúléró mi, Ìwọ Ìmúrasílẹ̀ mi
Yo
يَاعُمْدَتِي ياعُدَّتِي
يامُنْقِذِي مِنْ شِدَّتِي
Opómúléró mi àti ìmúrasílẹ̀ mi
Olùgbàlà mi kúrò nínú ìpọ́njú mi
وَجَّهْتُ لَكَ وِجْهَتِي
عَجِّلْ بِغَوْثِي ياعَظِيمْ
Ọ̀dọ̀ Rẹ ni mo dojú kọ
Yara ran mi lọ́wọ́ Ìwọ Alágbára
وَسَخِّرِ الْأَسْبَابَا
وَذَلِّلِ الْصِّعَابَا
Tẹ gbogbo àwọn ọ̀nà lórí ba
Kí O sì mú gbogbo ìṣòro rọrùn
وَافْتَحْ لَنَا الْأَبْوَابَا
بِالْنَّصْرِ مِنْكَ ياكَرِيمْ
Ṣí àwọn ilẹ̀kùn oore fún wa
Pẹ̀lú ìṣẹ́gun láti ọ̀dọ̀ Rẹ Ìwọ Onínú-ure
وَرُدَّ كَيْدَ الْكَائِدِ
وَكُلَّ طَاغٍ مَارِدِ
Yí ète àwọn olóte sẹ́yìn
Àti gbogbo onírora apanilára
وَحَاسِدٍ مُعَانِدِ
بِحَقِّ سِرْ (طسٓمٓ )
Àti olùlara tí ó jẹ́ alágídí
Nítorí ọlá àṣírí (Tā Sīn Mīm)