رَبِّي لَهُ الْأَسْمَاءُ الْحُسْنَى
Olúwa mi ni ó ní àwọn orúkọ tí ó dára jù lọ.
Yo
رَبِّي لَهُ الْأَسْمَاءُ الْحُسْنَى
تُسَبِّحْ لَهُ الْأكْوَانْ
Olúwa mi ni àwọn orúkọ tí ó dára jùlọ jẹ́ Tirẹ̀
Gbogbo ìṣẹ̀dá ló ń ṣe àfọmọ fún Un
إِلَيْهِ يَرْجِعُ كُلُّ أَمْرٍ
كُلُّ زَمَانٍ وَكُلَّ مَكَانْ
Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ni gbogbo ọ̀rọ̀ ń padà sí
Ní gbogbo àsìkò àti ní gbogbo àyè
إِذَا دَعَوْتْ فَادْعُ الْإِلَهْ
وَإِنِ اسْتَجَرْتَ فَلُذْ بِاللَّهْ
Bí o bá pè, pe Ọlọ́run Olúwa
Bí o bá sì wá ààbò, sá di Ọlọ́run
مَا لَنَا مَوْلًى سِوَاهْ
عَفُوٌّ كَرِيمٌ وَرَحْمَانْ
A kò ní Alápòló kankan lẹ́yìn Rẹ̀
Olùdáríjì, Aláàánú, àti Ọba Ìkẹ́
رَبِّي لَهُ الْأَسْمَاءُ الْحُسْنَى
تُسَبِّحْ لَهُ الْأكْوَانْ
Olúwa mi ni àwọn orúkọ tí ó dára jùlọ jẹ́ Tirẹ̀
Gbogbo ìṣẹ̀dá ló ń ṣe àfọmọ fún Un
إِلَيْهِ يَرْجِعُ كُلُّ أَمْرٍ
كُلُّ زَمَانٍ وَكُلَّ مَكَانْ
Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ni gbogbo ọ̀rọ̀ ń padà sí
Ní gbogbo àsìkò àti ní gbogbo àyè
اتَّقِ اللَّهْ وَلَهُ اِصْبِرْ
فَالْصَّبْرُ فِي الْعُقْبَى حَمِيدْ
Bẹ̀rù Ọlọ́run kí o sì ṣe sùúrù nítorí Rẹ̀
Nítorí pé sùúrù ní òpin rere tí ó lẹ́wà
وَتَزَوَّدْ عِلْمًا وَبَيَانًا
مِنَ الْسُّنَّةِ وَالْقُرْآنْ
Kó ìmọ̀ àti ìjìnlẹ̀ òye jọ bí ohun èlò
Láti inú Sunnah àti inú Al-Ƙur'ān