صَلَّى اللَّهْ عَلَيْكَ يَا نُور
Blessings Of Allah Be Upon You, O Light
Yo
صَلَّى اللَّهْ عَلَيْكَ يَا نُور
يَا نُوْرَ كُلِّ الْمَنَازِلْ
K'ike Ọlọrun maa b'o iwọ Imọlẹ
Iwọ imọlẹ gbogbo awọn ibugbe
يَا خَيْرَ مَنْ فِي الْمَنَازِلْ
Iwọ ẹni t'o loore ju ninu awọn olubugbe
يَا رَسُوْلَ اللٰهِ أَنْتَ
أَنْتَ الْنُّوْرُ الْمُتَشَكِّلْ
Iwọ Ojiṣẹ Ọlọrun, iwọ ni
Iwọ ni imọlẹ t'o gbe irisi jade
نُورٌ عَلَى نُورٍ جِئْتَ
بِهِ الْقُرْآنُ تَنَزَّلْ
Imọlẹ lori imọlẹ ni o fi de
Pẹlu rẹ ni Al-Qur’ani sọkalẹ
مِشْكَاةً نُوْراً وَزَيْتَا
ضِيَاءً جِئْتَ مُعْتَدِلْ
Atupa, imọlẹ ati ororo
Imọlẹ didan ni o mu wa ni pipe
لَا يَكُوْنُ الْكَوْنُ حَتَّى
يَظْهَرْ بِكَ مُتَجَمِّلْ
Ayé kò níí sí títí tí
Yóò fi fara hàn ní ẹni t'o l'ẹwà nípasẹ̀ rẹ
أَنْتَ فِي الْآثَارِ قُلْتَ
ذَا الْكَوْنُ مِنْكَ تَمَثَّلْ
Iwọ lo sọ ninu awọn ọrọ atijọ
Wipe gbogbo ayé yii wa lát'ọdọ rẹ
مِنْ حَضْرَةِ الْقُدْسِ جِئْتَ
وَأَنْتَ فِيهَا لَمْ تَزَلْ
Lati itẹ mímọ́ ni o ti wá
Iwọ sì wà níbẹ̀ láì yẹsẹ̀
كُنْتَ قَبْلَ الْكَوْنِ كُنْتَ
وَالأَبَدُ مِثْلُ الأَزَلْ
O ti wà ṣáájú kí ayé tó wà
Ìgbà àìnípẹ̀kun sì dàbí ìgbà àtijọ́
مُطْلَقاً كُنْتَ فَصِرْتَا
بِالْقُيُوْدِ مُتَجَمِّلْ
Aláìní-ìhámọ́ ni ọ́, o sì wá di
Ẹni t'o l'ẹwà nínú ìhámọ́ ẹ̀dá
لَيْسَ فِي الْوُجُودِ الْبَتَّةْ
إِلَّا الْنُّورُ قُلْتُ أَجَلْ
Kò sí ohun kan nínú ìṣẹ̀dá rárá
Bí kò ṣe Imọlẹ, mo sì wípé bẹ́ẹ̀ ni
بَدَا مِنَ الْغَيْبِ بَغْتَةْ
مِنْ أَعْلَى الْعُلَا تَنَزَّلْ
Ó yọ jáde láti inú ìkọ̀kọ̀ lójijì
Láti ibi gíga jùlọ lo ti sọkalẹ
يَا رَسُوْلَ اللهِ حُزْتَا
فَضْلَ الْفَضْلِ وَالْفَضَائِلْ
Iwọ Ojiṣẹ Ọlọrun, o ti jèrè
Oore-ọfẹ t'o ga jù ati awọn ìwà rere
يَا رَسُولَ اللَّهِ دُمْتَ
وَدُمْتُ لَكَ مُمَتَّثِلْ
Iwọ Ojiṣẹ Ọlọrun, kí o máa wà títí
Kí èmi náà sì máa tẹ̀lé àṣẹ rẹ
فَالْعَلَاوِيِ يَرْجُو حَتَّى
يَبْلُغْ بِرِضَاكَ الأَمَلْ
Al-Alawi ń nírètí títí tí
Yóò fi rí ìrètí gbà nípa ìtẹ́wọ́gbà rẹ
يَا رَسُوْلَ اللهِ أَنْتَ
أَنْتَ الْنُّوْرُ الْمُتَشَكِّلْ
Iwọ Ojiṣẹ Ọlọrun, iwọ ni
Iwọ ni imọlẹ t'o gbe irisi jade