ْيَاجَمَالُه
Oh, How Beautiful He Is!
Yo
آه يَا جَمَالُه يَا جَمَالُهْ
سِيدْنَا النَّبِى يَا جَمَالُهْ
Háà, ẹwà rẹ̀, ẹwà rẹ̀ o
Olúwa wa Ànábì, ẹwà rẹ̀ ò lẹ́gbẹ́
سِيدْنَا النَّبِى يَا جَمَالُهْ
Olúwa wa Ànábì, ẹwà rẹ̀ ò lẹ́gbẹ́
كَحِيلُ الطَّرْفِ حَبِيبِي لَوْ تَرَاهُ
ضَحُوكُ السِّنِّ لِلْعَاشِقِ رَمَاهُ
Olùfẹ́ mi ní ojú dudu tìrélí bá o bá rí i
Ẹ̀rín rẹ̀ adùn mọ́ni ni ó fi dẹkùn mú olùfẹ́
بَهِيُّ الطَّلْعَةْ فَالْمَوْلَى اصْطَفَاهُ
وَكُلُّ الْخَلْقِ أَنَارَ بِنُورِ طه
Arẹwà ní ìfarahàn ni ẹni tí Ọba Olúwa yàn
Gbogbo ìdásí ni ó tànmọ́lẹ̀ pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ Taha
وَلَا ظِلُّ لَهُ بَلْ كَانَ نُوْرَا
تَنَالَ الشَّمْسُ مِنْهُ هُوَ الْبُدُوْرَ
Kò ní òjìji rárá, dípò bẹ́ẹ̀ ìmọ́lẹ̀ ni
Oòrùn ń rí ìmọ́lẹ̀ gbà látọ̀dọ̀ rẹ̀, òun ni òṣùpá tòrò
وَلَمْ يَكُنِ الْهُدَى لَوْلَاهُ ظُهُوْرَا
وَ كُلُّ الْكَوْنِ أَنَارَ بِنُوْرِ طَــــــهَ
Ìmọ̀nà kì bá tí farahàn láìsí òun
Gbogbo àgbáyé sì tànmọ́lẹ̀ pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ Taha
وَكَفُّ الْمُصْطَفَى كَالْوَرْدِ نَادِى
وَعِطْرُهَا يَبْقَى إِذَا مَسَّتْ أَيَادِى
Atẹ́lẹwọ́ Al-Mustafa dàbí òdòdó tura
Òfìnrìn rẹ̀ á máa sára bá bá fọwọ́ kànwọ́
وَعَمَّ نَوَالُهَا كُلَّ الْعِبَادِ
حَبِيبُ اللهِ يَا خَيْرَ الْبَرَايَا
Ore rẹ̀ sì kárí gbogbo àwọn ẹrú
Olùfẹ́ Ọlọ́run, ìwọ ẹni rere jù nínú ìṣẹ̀dá
وَرِيقُ الْمُصْطَفَى يَشْفِي الْعَلِيلَ
وَعَيْنُ قَتَادَةَ خُذْهَا دَلِيلًا
Itọ́ Al-Mustafa ń wo aláìsàn sàn
Ojú Qatadah, mú un gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí
تَفَلَ فِي الْبِئْرِ أَضْحَتْ سَلْسَبِيلًا
وَصَارَ لِصَحْبِهِ شَهْدًا مُدَامًا
Ó tọ́ sí inú kànga ó sì di omi Salsabil
Ó sì di oyin àti ohun mímu dídùn fún àwọn ọmọ-lẹ́yìn rẹ̀